Kuse – Psalmos ft. Kore
Ku'se Lyrics
[intro]
[verse]
Mo wo waju mi mo ri owo yin Mo wo eyin wo mo ri ife yin
Won wa bere lo wo mi pe bawo ni mo se se
Mo so fun won wipe eeeeee
{Emi na ko o olorun oba ma ni
Olo run oba ma ni Olorun oba ma ni} 2x
{Moni baba kan oo Moni baba kan ooo
Baba ara to mo iyi omo} 5x
[chorus]
{Oluwa ku ise {Ehhh ehhhh ehhhh Ku ise} 3x
} 2x
[vamp:]
Oooooooooo {Oni kan wi o subu mo roguro
Reterete o baba ku ise...} 3x
[chorus:]
{Oluwa ku ise (u'se) Mi bami ku ise (ku ise)} 2x
{Ku ise (u'se)} 4x
[vamp:]
{Oni kan wi o subu mo roguro Reterete o baba ku ise...} 3x
[bridge:]
{Mo de ya so pe o) 4x O ni kan se lo ore ki e mo (olu bi o ni)
Emi kan se lo ore ki mo mo (Mo de ya so pe oooo ehhh)
[interlude]
Eyin bi olode o ba kuOju ide re kin ru ikoriko
Ko sa aseyin olubori
Ato fi arati bi oke
Ti emi
A le mi no emi
Ti mo fi goke odo afara tanja
Ara efi oju ire wo mi
Eniya efi owo anu kan mi
Emi na ko..
sugbon Eledumare ni
Olorun mi ahhh
Baba mi
Eledumare
Ogba gba ti gba alara ilara
Oba aa ji ki
Oba aa ji rii
Ehhh eyin
Ehhh beeee
aaaah
[chant:]
Oni ko bi o su bu mo ro bi ooEterete ooo Baba ku ise
Oni kan wi o subu
maro guro ehhh
maro guro ehhh
Oooo…ooooooooooo
Mo de wa so pe
Mo de wa so pe
Mo de wa so pe
Mo de wa so pe
Mo de wa so pe
Mo de wa so pe
Mo de wa so pe
WATCH VIDEO
No comments:
Post a Comment